Preview only show first 10 pages with watermark. For full document please download

The Ifa For Protection

Descripción: rituales de proteccion de ifa

   EMBED


Share

Transcript

The Ifa for protection Akasà, akasá, akasã Aronikasako Ina ni ngbenu aso yo abe Itale ni ngbenu ile yo ida Adifa fun oka, odifun Ere, Oka ni ori ohun – ohun ni Ere ni ori ohun – ohun ni Aja Ogan ti oba jin, orí arare ni o njin le Aja okiti ti obajin, orí arare lo njin si Asasi pehinda ki olopa alasasi Ki ebo pa elebo Gbogbo eniti oba n bami se ota Okari Kan kan ni omode n te eru - isu, okankan, ki ota mi maku Translation Akasa, Akasa, Akasa Aronikasako The bed bug that lives in our clothes but still pierces us The itale (an underground insect) lives in the earth and weilds the sword (to cut us) Divined for Oka (Black mamba) Divined for Ere (Python) Oka said he is his head Ere said he is his head The ant hill that falls, falls upon itself The wall that falls, falls upon itself All black magic should return and go and kill the sender All those that make me their enemies A child carries a load yam tuber by tuber They should all die one by one. 8) OFO EYONU AIYE Akinoro awo ori ogun ode Koleja awo ode idewure Pó ye awo ode igbari Eda giri giri awo ode iwafin Awon mererin omo ikofa orunmila niwonse Won wa sawo lo sapa okun ohun ilaji Meji osa, won gbagun okun, won gbagun ide, Won gba ola win ni win ni aso Nigbati won ko de Won wa paju otada si orunmila, Won fi ojojo ba orunmila ja Orunmila sun ori apere loju o run, Baba ji oso ode iponrire kale oransepe Odimodimo onikiwon wa dafa fun oun Wonkori ohun meji oOsameji ni won ri, Won ni akin oro nko? Baba ni omo iko fa oun nise, Won ni koleja nko? Babani omo iko fa oun nise, Won ni poye nko? Baba ni omo ikofa oun nise Won ni eda girigiri nko? Baba ni omo ikofa oun nise Won ni awon wonyi ni won nba orunmila se ota. Orunmila ni haa bi oba ribe oni kiwon ku pata pata Akin oro ku odi eiye oyo Koleja ku odi eiye kowe eiye aje Poye ku odi eiye ogbin gbin Eda girigiri ku du odi owiwi Won wa ni awon ti mo pe Orunmila lopa awon, Won wa gbera won foro wa ba orunmila ja Won de oju ona tan, won se apa Won se ese won ko lee fomo, Ara wa niwon pupo, Orunmila wa nrinlo sode, Baba bawon ni bi ti won gbe selapa selese si Won wa nbe orunmila Won ni orunmila dakundabo awon koni ba o jamo lailai Orunmila ni bi abari eleiye keleiye tabi emere kemere ti oba Tun da oju ija kowa nko? Won ni odimule o Woni won ase Lapa lese won koni gbadun rara titi won yio fi ku Sugbon ki orunmila ma pa ese Orunmila ni kosa ma pese won ni awo tun ku awo amosun awo amore otun ku awo Osunsun tere- eyi tinse awo igi egungun Translation? ……….. Akinoro the awo of Ori Ogun Ode Koleja the awo of Ode idewure Poye the awo of Ode igbari Eda giri giri the awo of Ode iwafin The four of them were ifa apprentices of Orunmila They went to divine towards the way to the ocean At half sea They collected 20 ropes (okun) They collected 20 pieces of bronze (ide) They collected wealth in the form of clothe When they returned with wealth They returned to orunmila as enemies They used ojojo to fight orunmila (spiritually) Orunmila slept and saw the signs in a dream Baba (Orunmila) woke up and called on his iponri Then he sent for Odimodimo, he said they should come and divine for him They didn’t see anything but osameji (in the oracle) They asked of Akin oro Baba (orunmila) said he was his apprentice They asked of Koleja Baba said he was his apprentice They asked of poye Baba said he was his apprentice They asked of eda giri giri Baba said he was his apprentice They said these are the people fighting orunmila Orunmila said haa if that is the case then they must all die Akin oro died and became the bird Oyo Koleja died and became the kowe the witch bird (looks like a bat but flies in the day) Poye died and became the bird ogbin gbin Eda giri giri died and became the bird owiwi (owl) They (enemies) now said they know that it is orunmila that killed them They now came in full force to fight orunmila When they got on the way The wings and legs couldn’t move They were now in great pain Orunmila was on his way out Baba (Orunmila) met them where they were struggling to move They now started to beg orunmila Please have mercy we will never ever fight you again Orunmila now asked what if we come across a witch or astral mate that wants to fight us? They responded that this will be our pact Such (witch, wizard, astral mate etc) will lose both hands and legs And will be in pain till death But orunmila must always do ebos (sacrifice) Orunmila said he should sacrifice They said awo (members of the same cult) remains, Awo amosun, awo amore (the grateful one), It remain awo osunsun tere (a plant) Which is the awo of the masquerades (egungun - they use to flog themselves with the stem of this plant) 9) IFA AYAJO – OBI OLOJU META Obi Oloju Meta EPO Iba, jini iwo lomo bibi inu won Ni ilu awusa (3 time ) Epe iwo lomo bibi inu won Ni ilu ijebu ( 3 time ) Ase iwo lomo bibi inu won Ni ilu ekiti efon ( 3 time ) Ase iwo lomo bibi inu won Ni ilu ota Nigba ti jini omo bibi Inu won nilu awusa Gbogun ti Orunmila, Orunmila pa jini O yo okan jini o fi ro epo je (3 times) Nigba ti epe omo bibi Inu won ni ilu ijebu gbogun Ti Orunmila, Orunmila pa Epe o fi okan re ro Epo je ( 3 time ) Nigba ti ase omo bibi Inu won gbogun ti Orunmila, Orunmila pa ase o fi okan ase Ofi ro epo je Nigba ti aje gbe ogun Ti Orunmila, Orunmila Pa aje ofi okan aje ro epo je Emi ( name ) Ni mon fi okan yin Ro epo je loni yi o OBI Translation Iba (A way of greeting with honour and respect the great powers that be) Jini you originate from hausa land (a place in africa) 3xs Epe (curse) you originate from Ijebu land (a place in yoruba land) 3xs Ase you originate from Ekiti Efon (a place in yoruba land) 3xs Ase you originate from Ota (a place in yoruba land) {When Jini the one from hausa land fought with orunmila Orunmila killed jini, removed his heart and eat it with palm oil} 3xs {when Epe the one from ijebu land fought with orunmila Orunmila killed epe, removed his heart and eat it with palm oil} 3xs When ase their child fought with orunmila Orunmila killed ase, removed his heart and eat it with palm oil When the witch fought with orunmila Orunmila killed the witch, removed his heart and eat it with palm oil I (name) have eaten your heart with palm oil today. IFA AYAJO On Fua Obi IFA = Iba, Eke ni pa eru ( 3 times ) Iyan jija ni pa iwofa ( 3 times ) Awon wonyi ni won difa Fun ori yomi nigba ti nbe Larin ota Won ni ota nbe ni waju Won ni ota nbe ni eyin Won ni oriyomi bawo lo se ma yo larin ota sikiti Ori yomi ni won le ba Ori yomi ni ori toun ni o yo oun Oni ___ nitori kini Oni tolobi ba mu obi Olojumarun dedi orisa Ni se ni won nyo ofua Re sile ni Ori yomi ni wo o yo oun Sile dandan ni Oni oso o yo oun sile Oni aje o yo oun sile Awon emere o yo sile Ki ori emi ( name) yo mi sile Ninu ibi omo araye o Ase Olodumare Olodumare ase | | | | | | | | Eji Ogbe Translation Iba Hypocrisy kills the slave (3xs) Argument kills the servant (3xs) They were the ones that divined for ori yomi (my head or luck saved me) When he was amongst enemies They said enemies in front Enemies at the back They asked ori yomi how will progress amidst all these enemies Ori yomi said they are trying But his head (luck) is saving him He said how could it be He said when a 5 pieced kolanut is taken to the dieties The Ofua is removed apart Ori yomi said i shall be kept apart It is a must The wizards shall kept me apart The witches shall keep me apart The astral mates (emere) shall keep me apart May the head of i (name) Save me from the Wickedness of men Ase from the creator ase.